Ìwé Oníwàásù 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ kún fún ìrora, iṣẹ́ rẹ̀ sì jẹ́ ìbànújẹ́ fún un. Ọkàn rẹ̀ kì í balẹ̀ lóru, asán ni èyí pẹlu.

Ìwé Oníwàásù 2

Ìwé Oníwàásù 2:17-26