Ìwé Oníwàásù 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé nígbà mìíràn ẹni tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹlu ọgbọ́n, ìmọ̀ ati òye yóo fi gbogbo rẹ̀ sílẹ̀ fún ẹni tí kò ṣe làálàá fún wọn. Asán ni èyí pẹlu, nǹkan burúkú sì ni.

Ìwé Oníwàásù 2

Ìwé Oníwàásù 2:14-25