Ìwé Oníwàásù 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà mo kórìíra ayé, nítorí gbogbo nǹkan tí ń ṣẹlẹ̀ láyé ń bà mí ninu jẹ́, nítorí pé asán ati ìmúlẹ̀mófo ni gbogbo wọn.

Ìwé Oníwàásù 2

Ìwé Oníwàásù 2:13-23