Ìwé Oníwàásù 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni mo sọ lọ́kàn ara mi pé, “Ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí òmùgọ̀ ni yóo ṣẹlẹ̀ sí èmi náà. Kí wá ni ìwúlò ọgbọ́n mi?” Mo sọ fún ara mi pé, asán ni eléyìí pẹlu.

Ìwé Oníwàásù 2

Ìwé Oníwàásù 2:11-17