Ìwé Oníwàásù 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Yàtọ̀ sí pé ọ̀jọ̀gbọ́n náà gbọ́n, ó tún kọ́ àwọn eniyan ní ìmọ̀. Ó wádìí àwọn òwe fínnífínní, ó sì tò wọ́n lẹ́sẹẹsẹ.

Ìwé Oníwàásù 12

Ìwé Oníwàásù 12:1-11