Ìwé Oníwàásù 10:19-20 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Oúnjẹ a máa múni rẹ́rìn-ín,waini a sì máa mú inú ẹni dùn,ṣugbọn owó ni ìdáhùn ohun gbogbo.

20. Má bú ọba, kì báà jẹ́ ninu ọkàn rẹ,má sì gbé ọlọ́rọ̀ ṣépè, kì báà jẹ́ ninu yàrá rẹ,nítorí atẹ́gùn lè gbé ọ̀rọ̀ rẹ lọ,tabi kí àwọn ẹyẹ kan lọ ṣòfófó rẹ.

Ìwé Oníwàásù 10