Ìwé Oníwàásù 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú òkun ni gbogbo odò tí ń ṣàn ń lọ, ṣugbọn òkun kò kún. Ibi tí àwọn odò ti ń ṣàn wá, ibẹ̀ ni wọ́n tún ṣàn pada lọ.

Ìwé Oníwàásù 1

Ìwé Oníwàásù 1:6-15