Ìwé Oníwàásù 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fi tọkàntọkàn pinnu láti fi ọgbọ́n wádìí gbogbo ohun tí eniyan ń ṣe láyé.Làálàá lásán ni iṣẹ́ tí Ọlọrun fún ọmọ eniyan ṣe lórí ilẹ̀ ayé.

Ìwé Oníwàásù 1

Ìwé Oníwàásù 1:6-18