Ìwé Oníwàásù 1:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọ̀rọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n, ọmọ Dafidi, Ọba Jerusalẹmu nìyí.

2. Asán ninu asán, bí ọ̀jọ̀gbọ́n ti wí, asán ninu asán, gbogbo rẹ̀ asán ni.

3. Èrè kí ni eniyan ń jẹ ninu gbogbo làálàá rẹ̀, tí ó ń ṣe nílé ayé?

4. Ìran kan ń kọjá lọ, òmíràn ń dé, ṣugbọn ayé wà títí laelae.

Ìwé Oníwàásù 1