Isikiẹli 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Ọlọrun kígbe sí mi létí, ó ní, “Ẹ súnmọ́bí, ẹ̀yin tí ẹ óo pa ìlú yìí run, kí olukuluku mú nǹkan ìjà rẹ̀ lọ́wọ́.”

Isikiẹli 9

Isikiẹli 9:1-11