Isikiẹli 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo wò, mo rí nǹkankan tí ó dàbí eniyan. Láti ibi tí ó dàbí ìbàdí rẹ̀ dé ilẹ̀ jẹ́ iná, ibi ìbàdí rẹ̀ sókè ń kọ mànàmànà bí idẹ dídán.

Isikiẹli 8

Isikiẹli 8:1-7