Isikiẹli 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ó mú mi lọ sí ẹnu ọ̀nà tí ó wà ní ìhà àríwá ilé OLUWA. Wò ó, mo rí àwọn obinrin kan níbẹ̀, tí wọ́n jókòó, tí wọn ń sunkún nítorí Tamusi.

Isikiẹli 8

Isikiẹli 8:4-18