Isikiẹli 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Òpin ti dé ba yín báyìí, n óo bínú si yín, n óo da yín lẹ́jọ́ gẹ́gẹ́ bí ìwà yín; n óo sì jẹ yín níyà nítorí gbogbo ìwà ìríra yín.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:1-4