Isikiẹli 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kó àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n burú jùlọ wá, wọn óo wá gba ilé wọn. N óo fi òpin sí ìgbéraga àwọn alágbára wọn, wọn yóo sì sọ àwọn ibi mímọ́ wọn di eléèérí.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:20-27