Isikiẹli 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkókò tó; ọjọ́ náà sì ti dé tán, kí ẹni tí ń ra nǹkan má ṣe yọ̀; bẹ́ẹ̀ ni kí ẹni tí ń tà má sì banújẹ́, nítorí ibinu ti dé sórí gbogbo wọn.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:3-14