Isikiẹli 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo da òkú ẹ̀yin ọmọ Israẹli sílẹ̀ níwájú àwọn oriṣa yín, n óo sì fọ́n egungun yín ká níbi pẹpẹ ìrúbọ yín.

Isikiẹli 6

Isikiẹli 6:2-6