Isikiẹli 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, èmi, OLUWA Ọlọrun fúnra mi, ni mo dójú le yín, n óo sì ṣe ìdájọ́ fun yín lójú àwọn orílẹ̀-èdè.

Isikiẹli 5

Isikiẹli 5:1-13