Isikiẹli 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba yóo máa pa ọmọ wọn jẹ láàrin yín; ọmọ yóo sì máa pa àwọn baba jẹ. N óo dájọ́ fun yín, n óo fọ́n gbogbo àwọn tí ó kù ninu yín káàkiri igun mẹrẹẹrin ayé.

Isikiẹli 5

Isikiẹli 5:1-16