Isikiẹli 48:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ àwọn ọmọ Lefi ati ilẹ̀ gbogbo ìlú yóo wà láàrin ilẹ̀ ọba. Ilẹ̀ ọba yóo wà láàrin ilẹ̀ Juda ati ti Bẹnjamini.

Isikiẹli 48

Isikiẹli 48:17-25