Isikiẹli 47:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá sọ fún mi pé, “Ìwọ ọmọ eniyan, ṣé o rí nǹkan?” Nígbà náà ni ó mú mi gba etí odò náà pada.

Isikiẹli 47

Isikiẹli 47:4-9