Isikiẹli 46:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ó wí fún mi pé, “Àwọn ilé ìdáná níbi tí àwọn alufaa tí óo wà níbi pẹpẹ yóo ti máa se ẹran ẹbọ àwọn eniyan mi nìyí.”

Isikiẹli 46

Isikiẹli 46:23-24