Isikiẹli 46:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba yóo bá wọn wọlé nígbà tí wọ́n bá wọlé, nígbà tí wọ́n bá sì jáde, yóo bá wọn jáde.

Isikiẹli 46

Isikiẹli 46:5-13