Isikiẹli 45:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà ọba yóo pa ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀ ati fún gbogbo àwọn ará ìlú.

Isikiẹli 45

Isikiẹli 45:15-24