Isikiẹli 45:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Ní ọjọ́ kinni oṣù kinni, ẹ pa ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan tí kò ní àbààwọ́n, kí ẹ fi ṣe ìwẹ̀nùmọ́ ibi mímọ́.

Isikiẹli 45

Isikiẹli 45:9-24