Isikiẹli 44:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò tọ́jú àwọn ohun mímọ́ mi, àwọn àlejò ni ẹ ti fi ṣe alákòóso níbẹ̀.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:1-17