Isikiẹli 44:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọkunrin náà mú mi gba ẹnu ọ̀nà ìhà àríwá wá siwaju tẹmpili; mo sì rí i tí ìtànṣán ògo OLUWA kún inú tẹmpili, mo bá dojúbolẹ̀.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:2-12