Isikiẹli 44:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò gbọdọ̀ fẹ́ opó tabi obinrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀, àfi wundia tí kò tíì mọ ọkunrin láàrin àwọn eniyan Israẹli tabi opó tí ó jẹ́ aya alufaa.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:16-25