Isikiẹli 44:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọn kò gbọdọ̀ fá irun orí wọn tabi kí wọn jẹ́ kí oko irun wọn gùn, wọn yóo máa gé díẹ̀díẹ̀ lára irun orí wọn ni.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:18-22