Isikiẹli 43:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọkunrin náà ti dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ mi, mo gbọ́ tí ẹnìkan ń bá mi sọ̀rọ̀ láti inú Tẹmpili, ó ní:

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:2-8