Isikiẹli 43:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá ti yà á sí mímọ́ tán, ẹ óo mú akọ mààlúù tí kò ní àbààwọ́n ati àgbò tí kò ní àbààwọ́n láti inú agbo ẹran, ẹ óo fi rú ẹbọ.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:13-27