Isikiẹli 43:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo mú akọ mààlúù ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀; ẹ óo sun ún ní ibi tí a yàn lára ilẹ̀ Tẹmpili ní ìta ibi mímọ́.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:14-22