Isikiẹli 43:19 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ óo fún àwọn alufaa, ọmọ Lefi, láti inú ìran Sadoku, tí wọn ń rú ẹbọ sí mi, ní akọ mààlúù kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Isikiẹli 43

Isikiẹli 43:9-27