Isikiẹli 42:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn yàrá ti àgbékà kẹta kéré, nítorí ibùjókòó-òkè ti àgbékà kẹta fẹ̀ ju àwọn tí wọ́n wà níwájú àwọn yàrá àgbékà kinni ati ti àgbékà ààrin lọ.

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:4-15