Isikiẹli 42:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Òòró ilé tí ó wà ní ìhà àríwá náà jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50), ìbú rẹ̀ sì jẹ́ aadọta igbọnwọ (mita 25).

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:1-10