Isikiẹli 42:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó yipada, ó wọn ìhà àríwá, ó jẹ́ ẹẹdẹgbẹta (500) igbọnwọ (mita 250), gẹ́gẹ́ bí ọ̀pá rẹ̀.

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:10-20