Isikiẹli 42:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ti parí wíwọn inú Tẹmpili, ó mú mi gba ẹnu ọ̀nà tí ó kọjú sí ìlà oòrùn jáde, ó sì wọn ẹ̀yìn Tẹmpili yíká.

Isikiẹli 42

Isikiẹli 42:14-20