Isikiẹli 41:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wọn òòró yàrá náà, ó jẹ́ ogún igbọnwọ, (mita 10), ìbú rẹ̀ sì jẹ́ ogún igbọnwọ (mita 10), níwájú ibi mímọ́ náà. Ó sì wí fún mi pé ìhín ni ibi mímọ́ jùlọ.

Isikiẹli 41

Isikiẹli 41:2-6