Isikiẹli 41:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni gígùn iwájú tẹmpili tí ó kọjú sí ìlà oòrùn ati àgbàlá, òun náà jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).

Isikiẹli 41

Isikiẹli 41:8-16