Isikiẹli 41:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ó mú mi lọ sí ibi mímọ́, ó wọn àtẹ́rígbà rẹ̀, ìbú rẹ̀ ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji jẹ́ igbọnwọ mẹfa (mita 3).

Isikiẹli 41

Isikiẹli 41:1-5