Isikiẹli 40:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kan àwọn ìkọ́ kan tí ó gùn ní ìwọ̀n àtẹ́lẹwọ́ kan mọ́ ara tabili yíká ninu. Wọn a máa gbé ẹran tí wọn yóo bá fi rúbọ lé orí àwọn tabili náà.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:36-49