Isikiẹli 40:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mi lọ sí ibi ẹnu ọ̀nà tí ó wà ní ìhà àríwá, ó sì wọ̀n ọ́n, bákan náà ni òun náà rí pẹlu àwọn yòókù.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:27-40