Isikiẹli 40:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú mi lọ sí apá ìhà gúsù, mo sì rí ẹnu ọ̀nà kan níbẹ̀. Ó wọn àtẹ́rígbà ati ìloro rẹ̀, wọ́n sì rí bákan náà pẹlu àwọn yòókù.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:20-26