Isikiẹli 40:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó ṣiwaju mi lọ sí ìhà àríwá; ó wọn ìbú ati òòró ẹnu ọ̀nà kan tí ó wà níbẹ̀ tí ó kọjú sí ìhà àríwá, tí ó sì ṣí sí àgbàlá òde.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:14-24