Isikiẹli 40:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mi wá sí ibi gbọ̀ngàn ti òde, mo rí àwọn yàrá ati pèpéle yíká àgbàlá náà. Ọgbọ̀n yàrá ni ó wà lára àgbàlá náà.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:13-27