Isikiẹli 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli yóo ṣe máa jẹ oúnjẹ wọn ní àìmọ́, láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tí òun óo lé wọn sí.”

Isikiẹli 4

Isikiẹli 4:10-17