Isikiẹli 39:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ìlú Israẹli yóo tú síta, wọn yóo dáná sun àwọn ohun ìjà ogun: apata ati asà, ọrun ati ọfà, àáké ati ọ̀kọ̀. Ọdún meje ni wọn yóo fi dáná sun wọ́n.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:8-11