Isikiẹli 39:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo gbàgbé ìtìjú wọn ati ìwà ọ̀tẹ̀ tí wọn hù sí mi, nígbà tí wọn bá ń gbé orí ilẹ̀ wọn láìléwu, tí kò sì sí ẹni tí yóo dẹ́rùbà wọ́n.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:19-29