Isikiẹli 39:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan ninu àwọn tí ń wá òkú kiri bá rí egungun eniyan níbìkan, yóo fi àmì sibẹ títí tí àwọn tí ń sin òkú yóo fi wá sin ín ní àfonífojì Hamoni Gogu.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:9-18