Isikiẹli 39:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí ń gbé ilẹ̀ náà ni yóo sin wọ́n, wọn óo sì gbayì ní ọjọ́ náà, nígbà tí mo bá fi ògo mi hàn. OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 39

Isikiẹli 39:9-23