Isikiẹli 38:21 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dá oríṣìíríṣìí ẹ̀rù ba Gogu, lórí òkè mi, àwọn ọmọ ogun rẹ̀ yóo fa idà yọ sí ara wọn. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 38

Isikiẹli 38:12-23